House of the Rising Sun
de Lysa Maff
Gbogbo owó tí mo na
Fún ọjọ' méje
Gbogbo owó tí mo na
Kò gbe ogungunnisọ fún mí
Èmi ọmọ oró, I no fit pass my lane
Wọn ni kin ma jáde, but wọn lé mi
Èmi ọmọ owó, I no do pass myself
Wọn ni kín má sáré, but wọn le mi-i
So, I can not see my brother Ojo
And popo them don lock my brother up o
Say, make them free my brothers, oh-oh
Them no kill person, them be ọmọ owó, oh
Ajé ogugulusọ o
Ah, o kúkú ni sọ fún mi
Ah, o kúkú ni sọ fún mi
Mo mọ pe o kúkú ni sọ fún mi
Gbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méje
Mo w'ọṣẹ dúdú, kọ ọjọ to lọ-ọ
Gbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méje
Mo w'ọṣẹ dúdú, ọjọ le lọ
Ah, ki ikú ma pa aláàánú mi
Ki ọta mi le ri ran wo
Ki ọta mi le ri ran wo
Ah, ki ikú ma pa aláàánú wa
Ki ọta wá le ri ran wo
Ki ọta wá le ri ran wo
Ah, ki ikú ma pa aláàánú mi
Ki ọta mi le ri ran wo
Ki ọta mi le ri ran wo
Ah, ki ikú ma pa aláàánú wa
Ki ọta wá le ri ran wo
Ki ọta wá le ri ran wo
I've been thinking, I've been too deep in my feelings
Bless my pocket, ṣé mi l'ọmọ t'ọ ma jí ri
If I no hustle who go take care of my siblings
If I no hustle who go take care of my siblings
Mo sare wọ Jerusalem, mo gbàdúrà ki n le pa'wo
If ọlọ́pàá no lock Ojo up, my brother he dey yawo
Man make man kàlà
Ẹjẹ lo jú mi
Man make man kala, ah
Ẹjẹ lo jú mi
Gbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méje
Mo w'ọṣẹ dúdú, kọ ọjọ to lọ-ọ
Gbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méje
Mo w'ọṣẹ dúdú, ọjọ le lọ
Ah, ki ikú ma pa aláàánú mi
Ki ọta mi le ri ran wo
Ki ọta mi le ri ran wo
Ah, ki ikú ma pa aláàánú wa
Ki ọta wá le ri ran wo
Ki ọta wá le ri ran wo
Más canciones de Lysa Maff
- No se encontraron más canciones del artista.